Psalms 118:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA wà pẹlu mi láti ràn mí lọ́wọ́, nítorí náà, n óo wo àwọn tí wọ́n kórìíra mi pẹlu ayọ̀ ìṣẹ́gun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa mbẹ fun mi pẹlu awọn ti nràn mi lọwọ: nitorina li emi o ṣe ri ifẹ mi lori awọn ti o korira mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA n bẹ fún mi; òun ni olùrànlọ́wọ́ mi Nítorí náà ni èmi ó ṣe rí ìfẹ́ mi lórí àwọn ti ó kórìíra mi.