Psalms 119:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ayọ̀ ń bẹ fún àwọn tí ìgbé ayé wọn kò lábàwọ́n, àní àwọn tí ń rìn gẹ́gẹ́ bí òfin OLUWA.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
IBUKÚN ni fun awọn ẹniti o pé li ọ̀na na, ti nrìn ninu ofin Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìbùkún ni fún àwọn ẹni tí ọ̀nà wọn wà láìlẹ́sẹ̀, ẹni tí í rìn ní ìbámu pẹ̀lú òfin OLÚWA,