Psalms 119:101 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N kò rin ọ̀nà ibi kankan, kí n lè pa òfin rẹ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo ti fà ẹsẹ mi sẹhin kuro nipa ọ̀na ibi gbogbo, ki emi ki o le pa ọ̀rọ rẹ mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ti pa ẹsẹ̀ mi mọ́ nínú gbogbo ọ̀nà ibi nítorí kí èmi lè gba ọ̀rọ̀ Rẹ.