Psalms 119:104 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nípa ẹ̀kọ́ rẹ ni mo fi ní òye, nítorí náà mo kórìíra gbogbo ìwà èké.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nipa ẹkọ́ rẹ emi ni iyè ninu: nitorina mo korira ọ̀na eke gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi rí òye gbà nínú ẹ̀kọ́ Rẹ; nítorí náà èmi kórìíra gbogbo ọ̀nà tí kò tọ́.