Psalms 119:118 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O ti kọ gbogbo àwọn tí ó yapa kúrò ninu ìlànà rẹ sílẹ̀, nítorí pé asán ni gbogbo ẹ̀tàn wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti tẹ̀ gbogbo awọn ti o ṣina kuro ninu ilana rẹ mọlẹ: nitori pe ẹ̀tan ni ironu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ kọ gbogbo àwọn tí ó sìnà kúrò nínú òfin Rẹ, nítorí ẹ̀tàn wọn asán ni.