bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 119:126
Psalms 119:126 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA, ó tó àkókò fún ọ láti ṣe nǹkankan, nítorí àwọn eniyan ń rú òfin rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, o to akokò fun ọ lati ṣiṣẹ: nitori ti nwọn ti sọ ofin rẹ di ofo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó tó àsìkò fún ọ láti ṣe iṣẹ́, OLÚWA; nítorí òfin Rẹ ti fọ́.