Psalms 119:128 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, èmi ń tẹ̀lé gbogbo ẹ̀kọ́ rẹ, mo sì kórìíra gbogbo ọ̀nà èké.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina emi kà gbogbo ẹkọ́ rẹ si otitọ patapata: emi si korira gbogbo ọ̀na eke.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí èmi kíyèsí gbogbo ẹ̀kọ́ òtítọ́ Rẹ̀, èmi kórìíra gbogbo ipa ọ̀nà búburú.