Psalms 119:129 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òfin rẹ dára, nítorí náà ni mo ṣe ń pa wọ́n mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iyanu li ẹri rẹ: nitorina li ọkàn mi ṣe pa wọn mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Òfin Rẹ̀ ìyanu ni: nítorí náà èmi gbà wọ́n gbọ́.