Psalms 119:136 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Omijé ń dà lójú mi pòròpòrò, nítorí pé àwọn eniyan kò pa òfin rẹ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Odò omi ṣàn silẹ li oju mi nitori nwọn kò pa ofin rẹ mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Omijé sàn jáde ní ojú mi, nítorí wọn kò gba òfin Rẹ̀ jẹ́ òtítọ́.