Psalms 119:152 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó pẹ́ tí mo ti kọ́ ninu ìlànà rẹ, pé o ti fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lati inu ẹri rẹ, emi ti mọ̀ nigba atijọ pe, iwọ ti fi idi wọn mulẹ lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Láti ọjọ́ pípẹ́ wá èmi ti kọ́ nínú òfin Rẹ tí ìwọ ti fi ìdí wọn múlẹ̀ láéláé.