bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 119:155
Psalms 119:155 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìgbàlà jìnnà sí àwọn eniyan burúkú, nítorí wọn kò wá ìlànà rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Igbala jina si awọn enia buburu: nitori ti nwọn kò wá ilana rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbàlà jìnnà sí àwọn ẹni búburú nítorí wọn kò wá àṣẹ Rẹ.