Psalms 119:167 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mò ń pa àṣẹ rẹ mọ́, mo fẹ́ràn wọn gidigidi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọkàn mi ti pa ẹri rẹ mọ́; emi si fẹ wọn gidigidi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi gba òfin Rẹ gbọ́, nítorí mo fẹ́ràn wọn púpọ̀ púpọ̀