Psalms 119:18 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Là mí lójú, kí n lè rí àwọn nǹkan ìyanu tí ó wà ninu òfin rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Là mi li oju, ki emi ki o le ma wò ohun iyanu wọnni lati inu ofin rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
La ojú mi kí èmi lè ríran rí ohun ìyanu tí ó wà nínú òfin Rẹ.