Psalms 119:20 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Òùngbẹ títẹ̀lé òfin rẹ ń gbẹ ọkàn mi, nígbà gbogbo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aiya mi bù nitori ifojusọna si idajọ rẹ nigbagbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọkàn mi pòrúúru pẹ̀lú ìfojúsọ́nà nítorí òfin Rẹ nígbà gbogbo.