Psalms 119:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O bá àwọn onigbeeraga wí, àwọn ẹni ègún, tí wọn kò pa òfin rẹ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti ba awọn agberaga wi, ti a ti fi gégun, ti o ti ṣina kuro nipa aṣẹ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ fi àwọn agbéraga bú, àwọn tí a fi gégùn-ún tí ó sìnà kúrò nínú àṣẹ Rẹ.