Psalms 119:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo yára láti pa òfin rẹ mọ́, nígbà tí o bá mú òye mi jinlẹ̀ sí i.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o ma sare li ọ̀na aṣẹ rẹ, nitori iwọ bùn aiya mi laye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi sáré ní ipa ọ̀nà àṣẹ Rẹ, nítorí ìwọ, ti tú ọkàn mi sílẹ̀.