Psalms 119:34 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Là mí lóye, kí n lè máa pa òfin rẹ mọ́, kí n sì máa fi tọkàntọkàn pa wọ́n mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fun mi li oye, emi o si pa ofin rẹ mọ́; nitõtọ, emi o ma kiyesi i tinutinu mi gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fún mi ní òye, èmi yóò sì pa òfin Rẹ mọ́ èmi yóò sì máa kíyèsíi pẹ̀lú ọkàn mi.