Psalms 119:49 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ranti ọ̀rọ̀ tí o bá èmi iranṣẹ rẹ sọ, èyí tí ó fún mi ní ìrètí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ranti ọ̀rọ nì si ọmọ-ọdọ rẹ, ninu eyiti iwọ ti mu mi ṣe ireti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Rántí ọ̀rọ̀ Rẹ̀ sí ìránṣẹ́ Rẹ, nítorí ìwọ ti fún mi ní ìrètí.