Psalms 119:51 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn onigbeeraga ń kẹ́gàn mi gidigidi, ṣugbọn n ò kọ òfin rẹ sílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn agberaga ti nyọ-ṣuti si mi gidigidi: sibẹ emi kò fa sẹhin kuro ninu ofin rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn agbéraga fi mi ṣe ẹlẹ́yà láì dádúró, ṣùgbọ́n èmi kò padà nínú òfin Rẹ.