bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Psalms 119:6
Psalms 119:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Òun ni ojú kò fi ní tì mí, nítorí pé òfin rẹ ni mò ń tẹ̀lé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li oju kì yio tì mi, nigbati emi ba njuba aṣẹ rẹ gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà, ojú kò ní tì mí nígbà tí mo bá ń kíyèsí àṣẹ Rẹ̀ gbogbo.