Psalms 119:63 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọ̀rẹ́ gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù rẹ ni mí, àní, àwọn tí wọn ń pa òfin rẹ mọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹgbẹ gbogbo awọn ti o bẹ̀ru rẹ li emi, ati ti awọn ti npa ẹkọ́ rẹ mọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi jẹ́ ọ̀rẹ́ sí gbogbo àwọn tí ó bẹ̀rù Rẹ, sí gbogbo àwọn tí ń tẹ̀lé ẹ̀kọ́ Rẹ̀.