Psalms 119:70 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọkàn wọn ti yigbì, ṣugbọn èmi láyọ̀ ninu òfin rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Aiya wọn sebọ bi ọrá; ṣugbọn emi o ṣe inu-didùn ninu ofin rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọkàn wọn yigbì kò sì ní àánú, ṣùgbọ́n èmi ní inú dídùn nínú òfin Rẹ.