Psalms 119:81 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo wá ìgbàlà rẹ títí, àárẹ̀ mú ọkàn mi; ṣugbọn mo ní ìrètí ninu ọ̀rọ̀ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọkàn mi ndaku fun igbala rẹ; ṣugbọn emi ni ireti li ọ̀rọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọkàn mi ń fojú sọ́nà nítorí ìgbàlà Rẹ, ṣùgbọ́n èmi tí mú ìrètí mi sínú ọ̀rọ̀ Rẹ.