Psalms 119:82 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Mo fojú sọ́nà títí, agara dá mi, níbi tí mo tí ń retí ìmúṣẹ ìlérí rẹ. Mo ní, “Nígbà wo ni o óo tù mí ninu?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju mi ṣofo nitori ọ̀rọ rẹ, wipe, Nigbawo ni iwọ o tù mi ninu?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ojú mi kùnà, pẹ̀lú wí wo ìpinu Rẹ; èmi wí pé, “Nígbà wo ni ìwọ yóò tù mí nínú?”