Psalms 119:86 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbogbo òfin rẹ ló dájú; ràn mí lọ́wọ́, nítorí wọ́n ń fi ìwà èké ṣe inúnibíni mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Otitọ li aṣẹ rẹ gbogbo: nwọn fi arekereke ṣe inunibini si mi: iwọ ràn mi lọwọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àsẹ Rẹ yẹ ní ìgbẹ́kẹ̀lé: rànmílọ́wọ́, nítorí ènìyàn ń ṣe inúnibíni sí mi láì nídìí.