Psalms 119:93 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lae, n kò ní gbàgbé ẹ̀kọ́ rẹ, nítorí pé, nípasẹ̀ wọn ni o fi mú mi wà láyé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lai emi kì yio gbagbe ẹkọ́ rẹ; nitori pe awọn ni iwọ fi sọ mi di ãye.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kì yóò gbàgbé ẹ̀kọ́ Rẹ láé, nítorí nípa wọn ni ìwọ ti pa ayé mi mọ́