Psalms 119:98 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìlànà rẹ mú mi gbọ́n ju àwọn ọ̀tá mi lọ, nítorí pé òun ni ó ń darí mi nígbà gbogbo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nipa aṣẹ rẹ iwọ mu mi gbọ́n jù awọn ọta mi lọ: nitori ti o wà pẹlu mi lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àṣẹ Rẹ mú mi gbọ́n ju àwọn ọ̀ta mi lọ, nítorí wọ́n wà pẹ̀lú mi láé.