Psalms 12:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Gbani, OLUWA; nítorí àwọn olódodo kò sí mọ́; àwọn olóòótọ́ ti pòórá láàrin àwọn ọmọ eniyan.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
GBÀ-NI Oluwa; nitori awọn ẹni ìwa-bi-Ọlọrun dasẹ̀; nitori awọn olõtọ dasẹ̀ kuro ninu awọn ọmọ enia.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ràn wá lọ́wọ́, OLÚWA nítorí ẹni ìwà bí Ọlọ́run kò sí mọ́; Olótìítọ́ tí pòórá kúrò láàrin àwọn ènìyàn.