Psalms 120:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo gbé! Nítorí pé mo dàbí àlejò tó wọ̀ ní Meṣeki, tí ń gbé ààrin àwọn àgọ́ Kedari.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Egbe ni fun mi, ti mo ṣe atipo ni Meṣeki, ti mo joko ninu agọ Kedari!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ègbé ni fún mi tí èmi ṣe àtìpó ní Mésékì, nítorí èmi gbé nínú àgọ́ Kédárì!