Psalms 122:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ti àwọn ará ati àwọn ẹlẹgbẹ́ mi, n óo wí pé, “Kí alaafia ó wà ninu rẹ.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori awọn arakunrin ati awọn ẹgbẹ mi, emi o wi nisisiyi pe, Ki alafia ki o wà ninu rẹ!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí àwọn ọkùnrin àti àwọn ẹgbẹ́ mi èmi yóò wí nísinsìyí pé, kí àlàáfíà kí ó wà nínú Rẹ̀;