Psalms 123:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣàánú wa, OLUWA, ṣàánú wa, ẹ̀gàn yìí ti pọ̀ jù!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa, ṣãnu fun wa, ṣãnu fun wa: nitori ti a kún fun ẹ̀gan pupọ̀-pupọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA, ṣàánú fún wa, ṣàánú fún wa; nítorí tí a kún fún ẹ̀gàn púpọ̀ púpọ̀.