Psalms 124:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Tí kì í bá ṣe pé OLUWA tí ó wà lẹ́yìn wa nígbà tí ọmọ aráyé gbógun tì wá,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iba máṣe pe Oluwa ti o ti wà fun wa, nigbati awọn enia duro si wa:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ìbá má ṣe pé OLÚWA tó wà ní tiwa,” Nígbà tí àwọn ènìyàn dúró sí wa: