Psalms 125:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Eniyan burúkú kò ní ní àṣẹ lórí ilẹ̀ àwọn olódodo, kí àwọn olódodo má baà dáwọ́ lé ibi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti ọpá awọn enia buburu kì yio bà le ipin awọn olododo: ki awọn olododo ki o má ba fi ọwọ wọn le ẹ̀ṣẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí ọ̀pá àwọn ènìyàn búburú kì yóò bà lé ìpín àwọn olódodo; kí àwọn olódodo kí o máa ba fi ọwọ́ wọn lé ẹ̀ṣẹ̀.