Psalms 125:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn OLUWA yóo fi irú ìyà àwọn aṣebi jẹ àwọn tí ó yà sí ọ̀nà àìtọ́. Alaafia fún Israẹli!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi o ṣe ti iru awọn ti nwọn yà si ipa ọ̀na wiwọ wọn: Oluwa yio jẹ ki wọn lọ pẹlu awọn oniṣẹ ẹ̀ṣẹ: ṣugbọn alafia yio wà lori Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó ṣe ti irú àwọn tí wọn yà sí ipa ọ̀nà wíwọ́ wọn; OLÚWA yóò jẹ́ kí wọn lọ pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀. Ṣùgbọ́n àlàáfíà yóò wà lórí Ísírẹ́lì.