Psalms 129:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọpọlọpọ ìgbà ni wọ́n ti ń pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi. Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ wí pé,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
IGBA pupọ̀ ni nwọn ti npọ́n mi loju lati igba-ewe mi wá, ni ki Israeli ki o wi nisisiyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi wá ni kí Ísírẹ́lì kí ó wí nísinsinyí