Psalms 129:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ọpọlọpọ ìgbà ni wọ́n ti ń pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi, sibẹ, wọn kò borí mi.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Igba pupọ̀ ni nwọn ti npọ́n mi loju lati igba-ewe mi wá: sibẹ nwọn kò ti ibori mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbà púpọ̀ ni wọ́n ti pọ́n mi lójú láti ìgbà èwe mi wá; ṣíbẹ̀ wọn kò tíì borí mi.