Psalms 129:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n to ẹgba sí mi lẹ́yìn, gbogbo ẹ̀yìn mi lé bíi poro oko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn awalẹ̀ walẹ si ẹhin mi: nwọn si la aporo wọn gigun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn awalẹ̀ walẹ̀ sí ẹ̀yìn mi: wọ́n sì là aporo wọn gígùn.