Psalms 129:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ojú yóo ti gbogbo àwọn tí ó kórìíra Sioni, a óo lé wọn pada sẹ́yìn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki gbogbo awọn ti o korira Sioni ki o dãmu, ki nwọn ki o si yi ẹhin pada.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí gbogbo àwọn tí ó korìíra Síónì kí ó dààmú, kí wọn kí ó sì yí ẹ̀yìn padà.