Psalms 13:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣùgbọ́n èmi gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀; n óo máa yọ̀ nítorí pé o óo gbà mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn emi o gbẹkẹle ãnu rẹ; ọkàn mi yio yọ̀ ni igbala rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n mo gbẹ́kẹ̀lé ìfẹ́ Rẹ tí kì í kùnà; ọkàn mi ń yọ̀ nínú ìgbàlà Rẹ.