Psalms 130:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ ní ìrètí ninu OLUWA! Nítorí pé ní ìkáwọ́ rẹ̀ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ wà, ní ìkáwọ́ rẹ̀ sì ni ìràpadà kíkún wà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Israeli iwọ ni ireti niti Oluwa: nitori pe lọdọ Oluwa li ãnu wà, ati lọdọ rẹ̀ li ọ̀pọlọpọ idande wà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísírẹ́lì, ìwọ ní ìrètí ní ti OLÚWA: nítorí pé lọ́dọ̀ OLÚWA ni àánú wà, àti lọ́dọ̀ Rẹ̀ ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdáńdè wà.