Psalms 131:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ ní ìrètí ninu OLUWA, láti ìsinsìnyìí lọ ati títí laelae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Israeli, iwọ ni ireti lọdọ Oluwa lati isisiyi lọ ati lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ísírẹ́lì, ìwọ ní ìrètí ní ti OLÚWA láti ìsinsinyí lọ àti láéláé.