Psalms 135:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹni tí ó pa orílẹ̀-èdè pupọ run; ó pa àwọn ọba alágbára:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o kọlu awọn orilẹ-ède pupọ̀, ti o si pa awọn alagbara ọba.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹni tí ó kọlu àwọn orílẹ̀ èdè púpọ̀, tí ó sì pa àwọn alágbára ọba.