Psalms 135:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Sihoni ọba àwọn Amori, Ogu ọba Baṣani, ati gbogbo ọba ilẹ̀ Kenaani.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sihoni, ọba awọn ara Amori, ati Ogu, ọba Baṣani, ati gbogbo ijọba Kenaani:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Síónì, ọba àwọn ará Ámorì, àti Ógù, ọba Báṣánì, àti gbogbo ìjọba Kénánì: