Psalms 135:14 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
OLUWA yóo dá àwọn eniyan rẹ̀ láre, yóo sì ṣàánú àwọn iranṣẹ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti Oluwa yio ṣe idajọ awọn enia rẹ̀, yio si ṣe iyọ́nu si awọn ọmọ-ọdọ rẹ̀,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí OLÚWA yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn Rẹ̀, yóò sì ṣe ìyọ́nú sí àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ Rẹ̀.