Psalms 136:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹni tí ó pa àwọn àkọ́bí ní ilẹ̀ Ijipti, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Fun ẹniti o kọlù Egipti lara awọn akọbi wọn: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Fún ẹni tí ó kọlu Éjíbítì lára àwọn àkọ́bí wọn; nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.