Psalms 136:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ó sì kó àwọn ọmọ Israẹli jáde kúrò láàrin wọn, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si mu Israeli jade kuro lãrin wọn: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì mú Ísírẹ́lì jáde kúrò láàrin wọn; nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.