Psalms 136:14 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó sì mú àwọn ọmọ Israẹli kọjá láàrin rẹ̀, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si mu Israeli kọja lọ larin rẹ̀: nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì mú Ísírẹ́lì kọjá láàrin Rẹ̀ nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.