Psalms 136:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ó pín ilẹ̀ wọn fún àwọn eniyan rẹ̀, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
O si fi ilẹ wọn funni ni ini, nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sì fi ilẹ̀ wọn fúnni ní ìní, nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.