Psalms 136:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
ó fún àwọn ọmọ Israẹli, iranṣẹ rẹ̀, nítorí pé ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ini fun Israeli, iranṣẹ rẹ̀; nitori ti ãnu rẹ̀ duro lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìní fún Ísírẹ́lì, ìránṣẹ́ Rẹ̀, nítorí tí àánú Rẹ̀ dúró láéláé.