Psalms 137:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
nítorí pé níbẹ̀ ni àwọn tí ó kó wa ní ìgbèkùn ti ní kí á kọrin fún àwọn. Àwọn tí ó ń pọ́n wa lójú sọ pé kí á dá àwọn lárayá, wọ́n ní, “Ẹ kọ orin Sioni kan fún wa.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoripe nibẹ li awọn ti o kó wa ni igbekun bère orin lọwọ wa; ati awọn ti o ni wa lara bère idaraya wipe; Ẹ kọ orin Sioni kan fun wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí pé níbẹ̀ ní àwọn tí ó kó wa ní ìgbékùn bèèrè orin lọ́wọ́ wá, àti àwọn tí ó ni wá lára bèèrè ìdárayá wí pé; ẹ kọ orin Síónì kan fún wa.